Ogun iferan si okunrin

Imule to daju Eye kowe dudu kan isu esuru pupa ati atare kan ,ao fi kowe dudu tele ape ao ko esuru lelori ao fi atare si o di jijo papo Lilo re; aofi oti Lo laro aofi epo pupa lo lale. Tested and confirmed, aje funwa o. Edan Aje:- ewe odunkun,ewe awede, ewe sekinimidin, ewe ESO,ewe sawerepepe, mariwo Ope, tete abalaye, efo gure, so rate edan meji, ako ati abo, so pa Gbogbo ewe yen po ninu ike funfun NLA kan ao wa da omi agbon topo le lori Pelu oti dry gin, ao wa ko edan mejeji si, ao ma fi omi yi we fun ojo meta, ni ojoketa tati we tan a ko edan na sori nkan kogbodo kanle ao wa fi eyele funfun Pelu eyetu bo awon edan na ao wa ko sinu Awo fun, ao ma fi ekuru se Sara fun edan yi ao si ma fi dry gin si ni gbakugba taba feran nise Pelu Adura, Edan Alaje ni.

Ekaro Gbogbo ile emi Omo yin ni Woli Opa mo npada bo. Fun ita tabi igbona, E lo wa ewe rinrin ki e lo loju olo, e pin so ona meji. On a keji,efi epo pupa die si, kie fi pa onitohun lara. Ki ama se fi pa atelewo pelu atelese.

Logo Olorun ara onitohun yio bale. Mosi tun she ebu oshole yi. A o wa eso bomubomu a o la tenre a oki N, tuntun ti a ka ti aworan eniyan inue koju si ita, pelu odidi atare kan bo inue ti koni han sita rara, a o wa jo, a o lo kuna, a o fi oti loo ni aro kutukuti ki ato ba enikankan soro, ni ihoho omo luabi.

A o se adura ohun ti a fe si kato loo.

THE HOME OF SUCCESS, HEALING AND TRADITIONAL MEDICINE

Eiye AWOKO, atare, sekere aloku ti koba si ileke larare mo, ao ha arare ao wa gun po mo atare naa ao wa yo okan eye AWOKO naa ao tun gun po mon oun ti ati gun naa yio Dabi agunmu ao ma fi oti oyinbo loo fun ojo mesan sugbon ti aba fe losi ibi Orin ao tun loo lo enina ma korin tio kori yio korin akogbayi, awon aye o siwona fun oooo. Aseje owo Ewe abamoda 3, pelu ata ijosi 9, a lo lori olo and fi po eyin agric 3, a wa da sinu nilonu ti won fi di sugar ao fi iyo die si, ao se jina, a o wa se adura si ki a to je.

Odaju Ose Get ewe iyalode funfun ati pupa 3 ,3 ti ko luju, a o lo pelu koun bilala die kan, a o wa lo lori olo a o wa fi ose ko, ti o ba di ni ale ao wa eki elewe a wa ge si meji, a o mu ti ori yen a o fi epo po ninu abo laifi omi si, a wa fi pa gbogbo ara lati ori, a o wa we ose na pelu kankan tutun.

Ao wa losun lale ojo na lai jade sita mon. Ogun iferan todaju Ota inun iroko,epo egusi ti obinrin se funra re,ao lo papo ao da sinu bintle ao ma fi para lo ba obinrin naa. Ogun iferan.

Borg warner 4 speed overdrive

September 05, BY ME AGBARA OMI Edan Aje:- ewe odunkun,ewe awede, ewe sekinimidin, ewe ESO,ewe sawerepepe, mariwo Ope, tete abalaye, efo gure, so rate edan meji, ako ati abo, so pa Gbogbo ewe yen po ninu ike funfun NLA kan ao wa da omi agbon topo le lori Pelu oti dry gin, ao wa ko edan mejeji si, ao ma fi omi yi we fun ojo meta, ni ojoketa tati we tan a ko edan na sori nkan kogbodo kanle ao wa fi eyele funfun Pelu eyetu bo awon edan na ao wa ko sinu Awo fun, ao ma fi ekuru se Sara fun edan yi ao si ma fi dry gin si ni gbakugba taba feran nise Pelu Adura, Edan Alaje ni.

Ao wa losun lale ojo na lai jade sita mon Ogun iferan todaju Ota inun iroko,epo egusi ti obinrin se funra re,ao lo papo ao da sinu bintle ao ma fi para lo ba obinrin naa.Wednesday, January 6, Ao ja ewe kan lori igi ibepe ti o so dada, ao bu die ninu iyepe oja ti o kun dada, erupe orita meta, ati erupe akitan ti o gba ore, ao gun po ao fi oyin gidi po, pelu ose ao fi omo ayo kan gun lori, ao ko sinu ike funfun ao ma fi we o daju.

AKOYA ABENU GONGO TOGBONA: ewe ailu, ewe kilofefimise, ewe mafowokan omo mi, ewe atikaparare, ewe gbegbe, ewe tete, awo ekun die, epo obo, odidin atare kan, ao lo wa ikaraun ibin to tobi ninu igbo, ibi ti won ba ge imo ewe ope eyin si, ni eti le saba ri ikaraun ibin, tabi ki e so fun awon elewe o mo ki won ba yin wa, amo ko je ti korofo ikaraun ibin tinu igbo gan gan, ao ko gbogbo awon eroja yi sii ikaraun ibin na. Ao fi aso pupa bo ooo loju, a o fi owu dudu ati funfun di ni iko bere ti ara re ko ni han sita, owu iranso lao lo ao lo ri mole si orita meta ni oru night fun ojo meta, to ba ti di ojo keta, ao lo wu kuro nibe ni ale, ao jo lai tu, ao lo kunnaa, ao da si meta, afi idan kan: sin gbere yii abadi wa ka, ao wa sin bere ejiogbe si center lona meta si isale re.

Ao fi idakeji: ao ko lose dudu, ao ko sinu iba funfun, after 7days, lao fi we ni ago kan osan lekan soso. AO FI IDA KETA: ao da sinu awo funfun ao we ni tira pelu owu dudu ati pupa, ao fi aso pupa ran ni olounde ao wa fi owu ibile dudu ati funfun we round ti olounde yen ko ni han jade, ao ma wo si ibadi, after 7days ti aba ti fi ose yen we ni ao ma wo siidi.

Ao si ni ma fi olounde yen we, ao ma bo remove ti aba fe we. Maran: ogun yii deenaa kiko aisan ni pa ibasun tabi ti won ba le magun fun obinrin, ti aba ba ni ajosepo, tabi ti won ba fi ogun gbawa, ko si nkan ti yo se wa aforan: ojo ti ijanba ba fe sele si wa, o le je ija n ba MOTO, tabi OLE, or OGUN war ti nkan ba sele si gbo gbo won, ko si ikan ti yio o sele si wa, lai fi arapa.

Sugbon eto itoju to muna doko wa fun ohun te beere sugbon kii se inkan ta le fi sori afefe. Orisi eto meta wa ti a ma n se ni sise n tele fun inkan omokunrin to ba kere tabi ko sise daada. E kan si mi lori e-mail Biiii eloooo niii.

Ao ma fi foko mu. Ao ba oogun na ro ejo ohun ti a fe ko sele ninu Ile naa. Newer Post Older Post Home. Subscribe to: Post Comments Atom.Print Send Add Share. Odumosu Ibadan, Nigeria Publication Date: [? Record Information Rights Management: This item is presumed to be in the public domain.

The University of Florida George A. Smathers Libraries respect the intellectual property rights of others and do not claim any copyright interest in this item. Users of this work have responsibility for determining copyright status prior to reusing, publishing or reproducing this item for purposes other than what is allowed by fair use or other copyright exemptions.

ASIRI IYO FUN IFERAN

Any reuse of this item in excess of fair use or other copyright exemptions may require permission of the copyright holder. PN Awure ti enia ma fi :. S"" Q. I, feran si Obitrin'. Iesllk-t dod S IsQye.

Congestion nasal biodescodificacion

SIriran - S lba - Agho Iba. Bi gmqde ba fi hu ehin Ti ara eSla ba wu Atesi, Aforan to daiu. ObIDi5 pada wa s ile. Afuojp obiria Amudo SOlu turn Qwq? SAdo dua Ti akoe ba. Page 30 AwvDn i Odnatkbn uximgati t. Y tli X ba fe lo, a ko gbQdo fi Qw9 lasan y Qfo re. Afeka laiye fe ina, aakaiye lorun nran. Qfq rq; Ogum.

Iwe egbogi iwosan

Sda bede 9-kQ ibigla, ole lonja ki o si ilg s 9 IC jai. Qf9 r:- QmQ origuo rente, iwo. Adk ti o.

Dayz explosives

Qe yi. QfQ re:-lIgba oigba awo alawo ni i. Qfo :-M nrifnto n-nfi ara re fun orisa, qyIa orob.

Chemical engineering calculations excel

Ofo rt- Tiu tebin m ni al iaf han Qlobun, ti. Qf re;: -Labalaba. Evpe s osi obinrin, ao bu ef y itQ nib, erupp idiamu dig, erup ihi ti adi? OYUN P ". Y 9Q 9gd-wwvq, o6nocri mariwo W oii arflt ugpn esusuapo fi ja ojiji so aL9b9 w.

QfQ r.To ba se ise yi wa ri wipe oda bi wipe osan gbese ara re yo fuye inu re yo si ma dun aje wipe ide tija niyen ELEYI NI ATUDE OWO AYE LARA Odaju gan ni ona yo si la gidi egbo tude die,die,isawuru metato ni omo ninu ao gun egbo tude po mo isawuru kan aogun mo ose iwe ekan pere ao se ekeji na be ao se eketa na be ao wa fi eyokan we ni owuro,ikan ni osan,ikan ni ale walah oori bi arare yo se ri nijo keji walahi.

Adie asa kan, Ewe mafowokanmomi tutu, Odindin atare nla kan, Sise re: Ao rora ge idi adie na roboto, ao ko ifun ati Edo re jade lati idi, Wednesday, January 6, OFORE: Siju womi, abifa gbuuru, siju womi la npe ifa, abifa gburu la npe esu odara, itun loni ki e fi enu rere tun mi se, ifa loni ki won fenu rere fami mora, ogbo loni ki won mu temi gbo,oro mi ka sai yo won ninu gerere, bi epo bafoju kan oorun ayo gerere, bi adi ba foju kan oorun ayo gererebi ori ba foju kan oorun ayo gerere bi awo ba fi oju kanna woranworan agun, bi oloko ba joko bi olobo ba debe a fi aye gba, Orisa sanu agbe o se aso re laro, orisa sanu aluko ose aso re losun, Ao se iwure fun ohun ti a fe.

Pelu Ase awon to laye, bi Ejo oka o ba ku, iru idi e kii fi sile lo.

ogun iferan si okunrin

OFO RE; Ope Eluju lo ko igba, lo ko Aake; difa fun Alaketu ti Otalele'gbesan eniyan nji ko otalele'gbesan edi ti, Ifa ni egun kegun ko tie lee mu mi, egun iyan kii modo, egun isu kii mobe, egun ina kii mu aaro, Ifa ni ariwo mi ti omo araye n pa ko ni le se buruku fun mi, ariwo ega susu kii pa Odan, Ifa ni ariwo roro ko ni se Oja ni nkan, Ifa ni temi ni tio ma se, ti ng o ma ni ire gbogbo, takese ni se lawujo owu, tijimere ni se lawujo gbogbo eranko.

O da ko Adebori ti ise yeye adan, t'o b'aro lomo sori igi. Oun ni Afomo! Beeni igi tio ba si fi ti afomo se, afomo naa nii pa!. Orunmila ni nje oro yi di kaka-ngbasa, mo ni o di onigikigi. Ifa ni "Igikigi kii maa ba Asunrin fori gbori. Eyin adie ki i dariso okuta, igbin kii dariso iyo.

Ina ki i dariso omi. Owo koko l'a fii wo igi. Owo orisa la fi i wo imole. Kujore Oluwatomisin ma di eni owo, E j'olowo o lo o.

Ogun Eyonu Awon Baba Wa Todaju

Afin ni Oluwatomisin, ki i se eni aa gba loju. Aro ni Oluwatomisin, ki i s'eni aa na. Abuke Orisa ni mi nki i seni aa di ni kanin-kanin. Ao lo awon meteeta ni otootoao ko po epo obo mose, ao wipe pe eyin aiye o, ao jewo Isele ti o sele si won bi a se n po mose, mo nbeyin lowe, mo si fe ki e ba mi se.

Ori ako okuta ni ao ti we.

Boudoir photo shoot tips

Awo ewure dudu, Irun abe, Ewe amunimuye, Odidi atare kan, Ekanna owo 10 ati ese 10Iru ipenpeju eniyen die, Irun ori die. Ao jo gbogbo re po ao ma fi sinu ounje tabi obe die fun eni naa, ti o ba ti je yio nife re.

Odaju Iba eyin agbagba, aye mujuba.

Htaccess allow cross origin specific domain

Unknown February 5, at AM. Baba ogbagba April 25, at AM. Unknown July 12, at AM. Newer Post Older Post Home. Subscribe to: Post Comments Atom.Adie asa kan, Ewe mafowokanmomi tutu, Odindin atare nla kan, Sise re: Ao rora ge idi adie na roboto, ao ko ifun ati Edo re jade lati idi, Wednesday, January 6, Ao ja ewe kan lori igi ibepe ti o so dada, ao bu die ninu iyepe oja ti o kun dada, erupe orita meta, ati erupe akitan ti o gba ore, ao gun po ao fi oyin gidi po, pelu ose ao fi omo ayo kan gun lori, ao ko sinu ike funfun ao ma fi we o daju.

AKOYA ABENU GONGO TOGBONA: ewe ailu, ewe kilofefimise, ewe mafowokan omo mi, ewe atikaparare, ewe gbegbe, ewe tete, awo ekun die, epo obo, odidin atare kan, ao lo wa ikaraun ibin to tobi ninu igbo, ibi ti won ba ge imo ewe ope eyin si, ni eti le saba ri ikaraun ibin, tabi ki e so fun awon elewe o mo ki won ba yin wa, amo ko je ti korofo ikaraun ibin tinu igbo gan gan, ao ko gbogbo awon eroja yi sii ikaraun ibin na.

Ao fi aso pupa bo ooo loju, a o fi owu dudu ati funfun di ni iko bere ti ara re ko ni han sita, owu iranso lao lo ao lo ri mole si orita meta ni oru night fun ojo meta, to ba ti di ojo keta, ao lo wu kuro nibe ni ale, ao jo lai tu, ao lo kunnaa, ao da si meta, afi idan kan: sin gbere yii abadi wa ka, ao wa sin bere ejiogbe si center lona meta si isale re.

Ao fi idakeji: ao ko lose dudu, ao ko sinu iba funfun, after 7days, lao fi we ni ago kan osan lekan soso. AO FI IDA KETA: ao da sinu awo funfun ao we ni tira pelu owu dudu ati pupa, ao fi aso pupa ran ni olounde ao wa fi owu ibile dudu ati funfun we round ti olounde yen ko ni han jade, ao ma wo si ibadi, after 7days ti aba ti fi ose yen we ni ao ma wo siidi.

Ao si ni ma fi olounde yen we, ao ma bo remove ti aba fe we. Maran: ogun yii deenaa kiko aisan ni pa ibasun tabi ti won ba le magun fun obinrin, ti aba ba ni ajosepo, tabi ti won ba fi ogun gbawa, ko si nkan ti yo se wa aforan: ojo ti ijanba ba fe sele si wa, o le je ija n ba MOTO, tabi OLE, or OGUN war ti nkan ba sele si gbo gbo won, ko si ikan ti yio o sele si wa, lai fi arapa.

Sugbon eto itoju to muna doko wa fun ohun te beere sugbon kii se inkan ta le fi sori afefe. Orisi eto meta wa ti a ma n se ni sise n tele fun inkan omokunrin to ba kere tabi ko sise daada. E kan si mi lori e-mail Biiii eloooo niii. Ao ma fi foko mu. Ao ba oogun na ro ejo ohun ti a fe ko sele ninu Ile naa.

ogun iferan si okunrin

Newer Post Older Post Home. Subscribe to: Post Comments Atom.Coming soon on 1st JUNE Ori akuko adie togbo dada ao fi sinu agbada ijo nkan ao ko ewe akoko bomole ao fi odidi atare kan si ao jo ao lo kuna ao da oyin si ao ma fi ika arin ropo ao ma la isoye yi dara otun sise fun awon omo keke tiwan lo ile iwe ao so wipe ki wan ki ika arin bo kiwan la, inu roba ti owo hand lewo la dasi ti ao ti mala OGUN TUDE TOODAJU.

Egbo lapa funfun ti ori akitan,Egbo lapa pupa ti won fi se ogba School ile iwe ,Aso funfun opa kan,opolo aye kan. Egbo lapalapa eyikeyii. Ao ge kekeke si inu ike kan.

Ao wa Alangba eyokan ao jo papo pelu odidi Atare kan ao lokuna dada. Ao wa da sinu egbo take kekeke yen Thehomeofsuccess gmail. The qualities of herbs are recognized for both spiritual and physical well-being. It is believed that the force that drives the universe, known as ASE, is in part locked up plant life awaiting use by those who have the knowledge to unlock it. The rites indigenous to the faith of the Yoruba could not exist without the herbs provided by Osanyin and the ASE within them.

It is by his invocation and permission that the primary rituals of consecration are realized. But his older brother Orunmila wanted Osanyin to feel worth. Orunmila arranged to leave Osanyin on the farm early in the morning with the instruction to pull weeds from between the rows of crops.

ogun iferan si okunrin

When Orunmila returned in the evening, he found Osanyin in the middle of the field weeping, without a single weed pulled. Orunmila asked his brother why he was weeping and why he had not completed his task. Orunmila was taken by surprise that his brother had such deep knowledge. Osanyin gifted each deity with the herbs and sacred knowledge most compatible with their individual spirits. When we view plants, most of us see only the outer green; it takes a person deprived of other senses and abilities to see the inherent energy within.

Osanyin, although lame, is powerful just the same. Through the deprivation of certain functions, he has been gifted with one more potent. His priests are distinctive, a cult not given to trance, as are the other cults. These priests speak through a direct link to their tutelary ORISHA as if their tongues were being rattled by a divine ventriloquism.

The deity has a strong association with birds, especially owls. This is not lost on Osanyin, whose knowledge is deeply esoteric. The iron staff by which an Osanyin priest is known often is shaped like plant branches shooting out of the ground, surmounted by a lone bird with wings spread in flight.

Osanyin is typically seen as a loner who wanders the fields. Osanyin is to himself, picking his herbs, and communing with nature. His messages and nature are enigmatic, like his voice. As we recognize, without Osanyin the rites of the Yoruba could not take place.

This is true whether the priest is in Yoruba-land or in the Diaspora. All rites must include herbs and plants of nature.Plss sir more of dis nd the 1 for protection nd healing people nd i wud lyk to no more abt eye aye. Ewe ategbo. Almighty god we continued to bless ur work ,I need awo igba arun that can cure any type of sickness. I really appreciate your effort may God eledumare continued to shower you blessing.

This is wonderful, may God bless more with this. What u gave free to us will be charge with a lot money in somewhere else. Pls, I hv a kid and almost 4yrs, he can't sit or walk up till now, he can't also talk. If there is anything you could help on this, I will appreciate. E jowo e fi oogun adult bedwetting to daju se aanu. Eni Sise O Lase Eledua. Ajinde ara o maa je o.

Ejowo sir,ti mo ba ti sun ti mo ba taji lati oju orun,mi o ki n le so oro,mi o ki n le da aragbe lati dide,o ma n da bi eni wipe,won de mi ni okun monle. Edakun baba kini ona abayo? Ajinde ara o ma je o. Edakun ejowo kini ona abayo? Ti mo ba taji lati oju orun,mi o ki n tete ni anfaani lati soro jade,ti mo ba fe so oro mi o ki n ni anfaani lati so oro,o ma n da bi eni wipe,won de mi ni okun monle lati ma le kuro ni oju kan.

Edakun e sanu mi o. Ori Inaki kan 2. Ori Ekun kan 3. Odindi Eiye Okin kan 4. Ori Ere Nla kan ati Ase re 5. Opolopo Ewe Orijin 6. Odindi Ataare 16 Ao jo gbogbo re po Ao da opolopo ewe Orijin yen le lori ao wa jo dadaa. Ao lo kunna. Eni ti o ni ogun yi ko gbudo je ninu Adiye yen Ao ma fi Oti Schinap lo Ogun yi ni dede ago am oru ni ojo meta meta Ao gbudo ba Obinrin lo po larin Ojo Meta lehin igbati aba lo ogun yen tan Obinrin ti o se unkan osu ko gbudo fi owo kan ose yen oo.

Orogbo, obi gbanja, etu ibon, ako okuta, esuru funfun, ege ti a nfi ngun iyan je, ogede agbagba dudu, agbado, iyere ao fi sugar die si ao gun po ao maa fi foko tutu mu. Ori aja gbigbe kan. Ao wafi


Thoughts to “Ogun iferan si okunrin

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *